Lẹ́yìn Ọlọ́run ìyàwó mi lo kan - Yemi Solade Olayemi Oniroyin 4/19/2018 01:36:00 am Add Comment Edit Yemi Solade lọ ṣe àfihàn ìyàwó rè pelu akole tó sọ wí pé, lẹ́yìn Ọlọ́run ìyàwó òun ni ènìyàn tó kàn ninu igbe ayé òun. Read More
Ọkùnrin to kọ mi silẹ lọ fẹ ọmọ komisanna tí di ọlọkada bayii- Liz Anjorin Olayemi Oniroyin 4/01/2018 01:32:00 pm Add Comment Edit Ọmọkùnrin kan lọ ń kabamọ lórí ayélujára wí pé òun ni àǹfààní láti fẹ́ ọmọ Dangote nígbà ti àwọn se agunbaniro ṣùgbọ́n sẹnsi òun kò ṣíṣe dáa... Read More
Lọ́jọ́ tí wọn fi Femi Branch jẹ Jagun Asa Olayemi Oniroyin 3/31/2018 07:30:00 am Add Comment Edit Won ni bí a kò ba rí ẹyẹ igun a gbọ́dọ̀ ṣebọ, bí a kò rí ẹyẹ akala a gbọdọ sorò, bí a kò bá ti rí ewé akòko kò sí bá a ti fẹ́ joyè nílẹ̀ yìí... Read More
Muyiwa Ademola tí padà sí kíláàsì gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ Olayemi Oniroyin 3/16/2018 03:37:00 am Add Comment Edit Kosi bí ènìyàn tí wù kó lọ́gbọ́n tàbí ní imọ, tí ẹnì náà kò ba ni ifarabalẹ, yóò nira fún irú ẹni bẹẹ láti sọ alaimọkan di onímò kíkún. Yàt... Read More
"Kosi ohun tó kàn mí pelu ayé Nìyí" - Toyin Abraham fàbínú yọ Olayemi Oniroyin 3/11/2018 02:47:00 pm Add Comment Edit Nígbà tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ń ro wí pé wàhálà láàárín Toyin Abraham àti Adeniyi Johnson tí rodo lọ mú mi, rúgúdù míì tú dabi wí pé ó fẹ́ súyọ pelu è... Read More