City People Magazine ṣetán láti dá Adegbodu Twins lọ́lá Olayemi Oniroyin 5/11/2018 02:54:00 pm Add Comment Edit Awon Aláṣẹ City People Magazine tí ṣetan láti ṣe ayẹyẹ idalọla fún àwọn ìbejì Adegbodu fún ipa ribiribi tí wón tí kò ti a ba n sọ nípa ojúló... Read More
Aṣọ Mercy Aigbe to dá wàhálà silẹ ni yìí Olayemi Oniroyin 5/10/2018 11:08:00 pm Add Comment Edit Àríyá... níbi ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Kemi Afolabi. Àwọn ènìyàn sọ wí pé aṣọ ti Mercy Aigbe wọ kò dára tó nígbà ti àwọn kan rí gẹ́gẹ́ bí oge lásán el... Read More
Odunlade Adekola yege: Irawo osere náà kàwé gboyè Olayemi Oniroyin 5/10/2018 11:01:00 pm Add Comment Edit Kò sí ìgbà táa dásọ tá rilẹ fiwọ́. Odunlade Adekola tí padà kàwé gboyè. Congratulations 🎊 Read More
Àṣírí isẹ tíátà Olayemi Oniroyin 4/25/2018 12:36:00 pm Add Comment Edit Asaraloge nínú ìṣe tíátà tí rekoja ká kún àtíkè funfun sì osere lójú, àwọn asaraloge to bá sha pra pra wọn a tún má sẹ da ẹ̀yà ara ènìyàn. O... Read More
Ohun tí ẹ kò mọ nípa Ayodeji Ibrahim Balogun (Wizkid) Olayemi Oniroyin 4/23/2018 01:11:00 pm Add Comment Edit Ohun tí ẹ kò mọ nípa Ayodeji Ibrahim Balogun (Wizkid) láti ọwọ́ Olayemi Olatilewa (Olayemi Oniroyin) Ọdún1990 ni wọn bí si ìdílé musulumi ... Read More