Simisola Omoayan: Omidan ti n filu dara Olayemi Oniroyin 11/21/2015 10:37:00 pm Add Comment Edit Simisola Omoayan O ti wa daju wi pe kosi oun ti okunrin se ti obirin o le se. Bi eniyan ba si foju kere ata, afaimo ki iru eni bee ma ... Read More
Gani Adams ti si Oodua Voice Redio niluu London Olayemi Oniroyin 11/21/2015 12:13:00 pm Add Comment Edit Awon Yoruba bo, won ni taa ba dojo, ojo a pe. Baa ba dosu, dandan ni kosu o ko. Ojo ketadinlogun osu yii (17/11/15) ni ile ise r... Read More
Otun Olubadan tile Ibadan ti dagbere faye Olayemi Oniroyin 11/20/2015 04:28:00 pm Add Comment Edit Oloye Omowale Kuye Otun Olubadan ti ile Ibadan, to tun je okan pataki ninu awon agba oye ile Ibadan, Omowale Kuye, ti dagbere faye len... Read More
Deji Akure ti won yo loye ti gbe Ijoba ipinle Ondo lo sile ejo Olayemi Oniroyin 11/14/2015 06:56:00 pm Add Comment Edit Adesina Adepoju Leyin odun marun-un ti ijoba ipinle Ondo ro Adesina Adepoju loye gege bi Deji tilu Akure, oba ilu Akure nigba kan ri n... Read More
Ooni tuntun wo ilu Ile-Ife tilu-tifon Olayemi Oniroyin 10/28/2015 10:39:00 pm Add Comment Edit Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti wo ilu Ile-Ife fun imurasile fun iwuye re ti o waye ni kopekope yii Read More