E wa wo ohun ti won se fun Ooni Ojaja nigba to fe mu omi niluu Amerika Olayemi Oniroyin 6/22/2016 07:05:00 pm Add Comment Edit Awon aworan Ooni Ogunwusi niyii ni Library of CONGRESS, nibi won ti da lola pelu ami-eye. Read More
Awon Foto Ooni Ogunwusi ni gbongan isembaye ile adulawo to wa ni Washington DC Olayemi Oniroyin 6/22/2016 06:45:00 pm Add Comment Edit Awon aworan Ooni Enitan Adeyeye Ogunwusi ni Smithsonian Museum of African Art to wa ni Washington DC niluu Amerika. Read More
Awon oyinbo fe fomi pana Sango olukoso niluu Amerika Olayemi Oniroyin 6/22/2016 06:13:00 pm Add Comment Edit Awon Onisango ni won parapo ni gbongan isembaye ile adulawo to wa ni Washiongton DC niluu Amerika lati bu ola fun Ooni Enitan Adeyeye... Read More
Onirinsa Ile-Ife fese rajo ni soosi RCCG ti Washington DC niluu Amerika Olayemi Oniroyin 6/20/2016 01:08:00 pm Add Comment Edit Lana, ojo kokandinlogun osu kefa odun, 19-06-2016, Ooni Enitan Ogunwusi, oba alaso funfun bi eye okin, fese rajo niwaju Oluwa ninu ij... Read More
Ayeye igbalejo ati idalola Ooni Ogunwusi ni Maryland, USA Olayemi Oniroyin 6/19/2016 07:32:00 am Add Comment Edit Obitibiti ero ni won ya wa pade Ooni Enitan Ogunwusi Adeyeye Ojaja II nikete to wo Maryland niluu Amerika. Read More