Asa dida ti wa tipe ninu orin ile Yoruba Olayemi Oniroyin 6/06/2017 11:09:00 pm Add Comment Edit Aimoye eroja lo kun inu orin kiko ko to di ohun taye gbo bi orin alarinrin. Iya elewe omo le saye wi pe, tewe agbo ko ba pe a maa... Read More
Alaye nipa ilu ti won pe ni gudugudu Olayemi Oniroyin 6/06/2017 10:59:00 pm 1 Comment Edit Gudugudu Kosi ba se fe so nipa iyan gidi ti n jo ni lowo lai so nipa isu iyan re, asoku alaye ni yoo si je lai menu ba odo to guns... Read More
Awon hausa se aponle Oonirinsa nipinle Jigawa Olayemi Oniroyin 5/06/2017 04:12:00 pm Add Comment Edit Eniyan to n wa owo lo to pade iyi lona, toba rowo sebi iyi naa ni yoo fi ra. Awon Hausa se aponle Ooni Ile Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi n... Read More
Awon omo ileewe Tai Solarin University of Education se abewo si Alaafin Oyo Olayemi Oniroyin 5/04/2017 11:05:00 pm Add Comment Edit Awon omo ileewe olukoni ifafiti Tai Solarin to kale si Ijebu Ode se abewo si Oba Lamidi Adeyemi laafin. Read More
Odun Ilu Ile Adulawo (African Drums Festival 2017 Olayemi Oniroyin 5/01/2017 08:20:00 pm Add Comment Edit Awon Yoruba bo, won ni okun ko le gun-ungun ko ma nibi o ti gbe sewa wa. Bi o tile je wi pe orisii awon eniyan kan ti n gbe ni... Read More