Ẹni kan lo ju èyí sì mi lórí whatspp. Ẹni moni loun ṣeni.
Read More
Home / Asa Yoruba
Showing posts with label Asa Yoruba. Show all posts
Showing posts with label Asa Yoruba. Show all posts
Ọwọ́ mẹ́wàá ni Ooni Ojaja kó fún Dangote àti Otedola
Èniyàn lè bá ọba lọ́wọ́ laye òde òní, kosi babara nibẹ. Níwòn ìgbà tí ẹni náà bá jẹ olówó tàbí ènìyàn pàtàkì láwùjọ. Mekunnu ni ko gbọ́dọ̀ d...
Read More
Ẹgbẹ́ Gani Adams tí lọ gbalẹ̀ nílùú Dubai
Gani Adams, Aare Ona Kankafo ilé Yorùbá, tí ṣe ifilole ẹgbẹ́ OPU, eléyìí tí ṣe adape orúkọ fún egbe OPC fún àwọn ìlú òkèèrè, siluu Dubai. O...
Read More
Omidan Ojuloge ń bó nílùú Ibadan nile Oluyọle
Lonii ojo aje, gbogbo wa la ma raje sohun rere. Aseti ki i bojo, aseti ki i boorun, aseti ko ni ba wa. Amin E ma gbagbe Omidan Ojuloge, igb...
Read More

Idahun ibeere Kayode @Ogundamisi: 'Ologbon di ori eja mu" ati "Gidigba osi ilekun"
Eku Owuro omo Karo o ji ire; ejo ki ni itumo owe Yoruba 'Ologbon di ori eja mu" ati "Gidigba osi ilekun"? — Kayode O...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)