Aso oge to da wahala sile niluu South Africa ni yii Olayemi Oniroyin 12/25/2015 12:25:00 pm Add Comment Edit Aworan obirin yii ti bere si ni di torofonkale lati igba to woso yii jade niluu South Africa. Bi awon eniyan se ri ni won ya foto re ti w... Read More
Se aso oge naa ni yii? Olayemi Oniroyin 11/28/2015 09:59:00 am Add Comment Edit Kini a le pe iru aso oge bayii? Se were alaso ni abi were alakisa? Pelu bi nnkan se n lo, se e lero wi pe to ba ya, awon eniyan ko ni ma ... Read More
Arambara aso oge Mercy Aigbe tun gbode Olayemi Oniroyin 11/20/2015 03:46:00 pm Add Comment Edit Mercy Aigbe lo ye ki won maa pe ni Omo-ojumo-kan-aso-oge-kan. E gba bee! Read More
Mercy Aigbe alaso oge pade Toke Makinwa Olayemi Oniroyin 11/15/2015 08:42:00 pm Add Comment Edit Awon Yoruba bo, won ni tode-tode ni i se alaso tuntun. Joojumo ni Mercy n sodun, Mercy Aigbe alaso oge. Mercy tun pade Toke, s... Read More
E wa woju orekelewa omoge Olayemi Oniroyin 11/12/2015 10:38:00 pm Add Comment Edit Omidan Toyin ni yii, orekelewa omoge ti n danilorun nigba gbogbo. Ti eyin naa ba ni foto to rewa bi eleyii, e fi sowo si wa ka gbe saye... Read More