Khloe Kardashian also oge ara otun Olayemi Oniroyin 5/29/2016 09:54:00 pm Add Comment Edit Aso oge Khloe Kardashian to je aburo omoge onibadi olokiki Amerika, Kim, ti wo inu iroyin amuludun agbaye. Aso yii ni omoge naa wo lana ... Read More
Awon omoge ti bẹrẹ si ni ya sokoto mo ara won ni fura bayii Olayemi Oniroyin 5/28/2016 05:51:00 pm Add Comment Edit Nje a le pe eleyii ni aso oge abi ibẹrẹ were? Read More
Opin aye ti de oo: Se aso oge naa ni yii? Olayemi Oniroyin 5/21/2016 01:11:00 pm Add Comment Edit Fun awon ti o ba fi oye ba awon aso oge igbalode wa lọ, ko ni joniloju wi pe iru aso yii ti de ile aye. Olomoge wo aso, o si si oyan sil... Read More
Se eyin ri iru gele bayii ri? Olayemi Oniroyin 5/21/2016 12:15:00 pm Add Comment Edit Onigele yii... Imura omobirin Yoruba atata ko ti pe lai si gele lori. Orisiirisii oge ni awon eniyan si n fi gele dalara lati mu gbay... Read More
Goolu Mercy Aigbe ta sansan Olayemi Oniroyin 5/19/2016 10:26:00 pm Add Comment Edit Aso oge awon amuludun ko tii pe lai si goolu gidi to je oju ni gbese. Eleyii ti won yoo wa sowo, wa sorun. Awon mii tile ma n be won ni... Read More