Abàmì ẹlẹ́dẹ̀ tí dífá fún Super Eagles nípa Russia 2018 Olayemi Oniroyin 6/15/2018 05:51:00 pm Add Comment Edit Ẹlẹ́dẹ̀ abàmì tó sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa wí pé, Donald J. Trump ìlú Amẹrika ni yóò jaye olubori gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà tí kéde wí pé ikọ́ a... Read More
Russia 2018: Pele àti Maradona tí wọlé Olayemi Oniroyin 6/12/2018 07:53:00 am Add Comment Edit Ààrẹ ìlú Russia 🇷🇺, Putin, fún ra rẹ lo kí Pele kaabọ si orile-ede Russia fún igbaradi ìfẹ́ agbaye tí yóò wayé ni or... Read More
"Mikel Obi kìí rán àwọn ènìyàn rẹ lọ́wọ́"- Ẹbi Mikel kan tí sọ̀rọ̀ Olayemi Oniroyin 5/10/2018 06:33:00 pm Add Comment Edit Ọmọkùnrin kan lórí ayélujára ti gbìyànjú láti fi aṣọ Mikel Obi yidọti. Ọmọkùnrin náà ṣe àlàyé ara rẹ gẹ́gẹ́ bí ọmọ àbúrò bàbà Mikel. Ó ni ar... Read More
Arsene Wenger tí kéde ifehinti rẹ Olayemi Oniroyin 4/23/2018 02:22:00 pm Add Comment Edit Ẹ kíyèsí, àlàyé to bá ti ní nọ́mbà kìí rújú. Nǹkan bí ọdún méjìlélógún lo fi tukọ̀ ẹgbẹ́ agbaboolu Arsenal gẹ́gẹ́ bí akonimọọgba. Igba mẹta ... Read More
Ọwọ Anthony Joshua, ọmọ ológo, ni àgbà wá báyìí Olayemi Oniroyin 4/01/2018 01:40:00 pm Add Comment Edit Ẹ wí fún ẹni tí kò bá mọ kí wọn lọ mọ wí pé, ọwọ́ Anthony Oluwafemi Olaseni Joshua nìkan ni ẹ ti lè rí àmì ẹyẹ agbaye WBA, IBF, WBO ati IBO.... Read More