Happy Birthday olùkọ́ mi: Apènà pé léèyàn Olayemi Oniroyin 4/12/2018 09:04:00 am Add Comment Edit Ẹ bá ma kí Apena, ẹ bá mi sọ fún olùkọ́ mi wí pé Olayemi mo wọn léèyàn pàtàkì. Bí ó bá lo igba ọdún láyé, ọdún kan ni wọn o fi ka fún ọ lóde... Read More
Happy Birthday! Mama Kunle Afolayan pé ní ọdún márùndínlọ́gọ́rin (75) Olayemi Oniroyin 4/03/2018 07:59:00 am 1 Comment Edit Mama Kunle Afolayan pé ẹni odùn márùndínlọ́gọ́rin láyé. A gbàdúrà ire àlàáfíà, ìdùnnú àti èmi gigùn fún mama. Igba ọdún, ọdún kan ni. Ha... Read More
O ti jasire: Bukola Oni tí diyàwó tuntun Olayemi Oniroyin 3/30/2018 07:55:00 pm Add Comment Edit Mi ò lọrẹ to pò, díẹ ni àwọn ọrẹ mi; lára wọn sì ni Bukky wá. Bukky a má lo inú kan, ó nifẹ àwọn ènìyàn, bákan ló jẹ́ akíkanjú obìnrin. Mo... Read More
Ènìyàn bí Rev. Mother Esther Abimbola Ajayi Olayemi Oniroyin 3/30/2018 08:56:00 am Add Comment Edit Rev. Mother Esther Abimbola Ajayi, adari ijo Love Of Christ Generation C&S to wá ni Clapham nílùú London ni ènìyàn pàtàkì wa fún ọsẹ ... Read More
#HappyBirthday Joke Muyiwa: Olùkọ́ àgbà iṣẹ́ tíátà tó pedegé! Olayemi Oniroyin 3/21/2018 01:47:00 pm 9 Comments Edit Àyàfi ti ènìyàn bá fẹ fi gba kan bọkan nínú ni yóò sọ wí pé Joke Muyiwa kii se agbaoje nínú ìṣe tíátà. Se àgbékalẹ̀ ni ka sọ ní àbí èdè líl... Read More