Tewe-Tegbo Yoruba: Itoju eti to n yo oyun Olayemi Oniroyin 8/16/2016 12:57:00 pm Add Comment Edit Ti eti ba dun enikan, ti eti naa ba n yo oyun, bayii ni a se le se iwosan re ni ilana ibile Yoruba. A ma wa Kokoro ika modu tanpeni ikan... Read More
Asiri: Nje eyin fe ki irun yin gun de ibadi? Olayemi Oniroyin 8/13/2016 06:18:00 pm Add Comment Edit Ti e ba fe ki irun yin gun de ibadi, ko tun ma wobo leyin bi oko reluwe, asiri ni yii. Awon eroja ti e ma wa ni yii: Omi ewe eti erin (... Read More
Ewe ati Egbo Yoruba: Eda oju ara obirin Olayemi Oniroyin 8/13/2016 05:52:00 pm Add Comment Edit Eroja: Oti Chelsea, red & yellow capsule ati ewe taba Ipase: E ra red & yellow capsule eyo mewaa (10pieces), e tu awon capsule ... Read More
Tewe-Tegbo Yoruba: Ogun Aran Olayemi Oniroyin 8/13/2016 11:04:00 am Add Comment Edit Aran ma n je ki ounje tete da lara eniyan, eyi si wa lara iwulo re si ara eniyan. Sugbon ti aran ba po lara, o tun le fa akoba. Idi ni... Read More
Ewe ati egbo Yoruba: fun Okun ati agbara Olayemi Oniroyin 8/12/2016 09:24:00 pm Add Comment Edit Boya eyin fe okun tabi agbara? Ohun ti e ma se ni yii. E ra 7up kan tabi Sprite igo kan pere. E da iyo sibi ijeun si inu re pelu miliki... Read More