Eji Ogbe Amber Rose Ranju Labe Aso Olayemi Oniroyin 3/19/2015 09:23:00 pm Add Comment Edit Ile ijo ni Amber Rose gba lo lale ana, oun ati bobo dudu kan ni won ri papo eni ti opolopo gba wi pe oseese ko je oko tuntun sisi olorin ... Read More
Kini Ẹsẹ Arabirin Ti Won Ja Si Ihoho Ni Ilu India? Olayemi Oniroyin 3/18/2015 09:06:00 pm Add Comment Edit Kini ohun ti omobirin naa tile le se gege bi ẹsẹ eleyii to le mu won se sakasaka bi eleyii? Gege bi iroyin ti gbe jade, ilu India ni ... Read More
Iya Eni Odun Merindinlogota (56) Bi Akobi Omo Re Leyin Odun Merindinlogbon(26) Ni Ile Oko Olayemi Oniroyin 3/18/2015 04:05:00 am Add Comment Edit Enikan lo gbe aworan yii sori ero Facebook lati se afihan ohun ti Olorun oga ogo ni agbara lati se ninu aye eda eniyan. Akole aworan naa... Read More
Ori Iya Mi oooooooooooo! Talo Ni Ukwu Yii? Olayemi Oniroyin 3/17/2015 09:20:00 pm Add Comment Edit Mo ni mo ri ukwu to ju ukwu lo, eyin ni ko ri bẹẹ. Nje eyin ri iru ukwu bayii ri loke yii? Bi iru ukwu bayii ba gbode, o ye ... Read More
Awon Omo Nigeria Ni Ilu China Yan Fun Buhari Olayemi Oniroyin 3/14/2015 11:57:00 pm Add Comment Edit Kii se Nigeria nikan ni won ti n March4Buhari, awon ti ilu China naa ti darapo mo won. Awon omo Nigeria ti won kekoo ni ilu China ti ... Read More