Adigunjale wọ Offa, wọn kówó, wọn tún fẹ̀mí ṣòfò Olayemi Oniroyin 4/06/2018 01:14:00 am 1 Comment Edit Àwọn adigunjale wọ ilu Offa lọjọ karùn-ún oṣù kẹrin ọdún yìí láti fọ banki. Àìmọye èmi lo ṣòfò, lára wọn ni ọlọ́pàá àti àwọn obìnrin. ... Read More
Ẹ wo bí wọn se pa àwọn ọmọdé nìpakúpa ni Taraba Olayemi Oniroyin 4/05/2018 01:01:00 pm Add Comment Edit Read More
Ohun tí àwon olopaa ṣe fún ìyá àgbàlagbà ni Abia ni yii Olayemi Oniroyin 4/05/2018 12:44:00 am Add Comment Edit Tí bá ń sọ nípa àwọn tí wọn wù ìwà ibajẹ, ó yẹ ká sọ nípa àwọn ọmọlúwàbí pẹ̀lú. Ní ìpínlè Abia, ìyá àgbàlagbà to ń bọ láti oko dá ẹyìn rẹ nù... Read More
Gómìnà ipínlẹ̀ Kano fi ori ru iyẹ̀pẹ̀ lónìí Olayemi Oniroyin 4/02/2018 08:33:00 pm Add Comment Edit Ẹnu yà ọ̀pọ̀lọpọ̀ lónìí nígbà tí gómìnà ipínlẹ̀ Kano, Abdullahi Ganduje, ṣe abewo si ise àkànṣe kan tí ń lọ lọ́wọ́. Gómìnà rí àwọn ènìyàn t... Read More
"Emir kìí se èdè Hausa", àlàyé Ọ̀jọ̀gbọ́n Farooq Kperogi tí ṣàlàyé ohun tó rújú Olayemi Oniroyin 4/02/2018 07:56:00 pm Add Comment Edit Ọ̀jọ̀gbọ́n Farooq Kperogi ọmọ Nàìjíríà tí ń sise olùkọ́ni ni ilu America tí ṣàlàyé wí pé, ìkà àbùkù nínà láàárín Yorùbá àti Haúsá láti ìgbà... Read More