Tinubu@66: Jagaban jùkò ọ̀rọ̀ sì PDP Olayemi Oniroyin 3/29/2018 08:15:00 pm Add Comment Edit "Àá tì sọ ohunkóhun PDP ni ka gbenudake. Òtítọ́ ni wí pé, fún ọdún mẹ́rìndínlógún ni PDP fi ja Nigeria lole, wọn kówó jẹ, wọn gbọnmu, w... Read More
ÌGBÈYÌN láti owó RASBAM (4) Olayemi Oniroyin 3/27/2018 03:33:00 pm Add Comment Edit - 4 - Àdìsá gbá owó tìdùnnútìdùnnú, ó dà a sí àpò, ó sin Balógun sí ònà, bó se padà dé ó ké sí Àjoké àti ìyá rè láti fi tó won létí. Àdìsá... Read More
Ohun tó mú Ibile 9ja Radio yàtọ̀ gédégédé ni yìí Olayemi Oniroyin 3/23/2018 09:18:00 am Add Comment Edit Lára àwọn ileese rẹdio orí ayélujára tí ń lewaju lákòókò yìí ni Ibile 9ja Radio, eléyìí tí òkìkí rẹ ń lọ sókè sí i láti ìgbà tí wọn ti bẹ̀r... Read More
Orisirisi ara lọ gbòde: Ẹ tún gbà eléyìí yẹ̀ wò Olayemi Oniroyin 3/23/2018 09:03:00 am Add Comment Edit Irú foto wo lé yìí Read More
Ẹ wá ohun tí abarapá abiyamọ ń ṣe lojoojumo Olayemi Oniroyin 3/23/2018 08:57:00 am Add Comment Edit Ìbéèrè tó kọ́kọ́ wá sí mi lọ́kàn ni wí pé níbo jí ọkọ obìnrin náà wá? Read More