Smiley face
Aṣọ oge asiko Adediwura Gold tí dá gobe silẹ

Aṣọ oge asiko Adediwura Gold tí dá gobe silẹ

Oserebirin Adediwura Becky Adesegha tí gbogbo ènìyàn mo sì Adediwura Gold lọ ṣe àfihàn àwòrán rẹ tuntun yìí. Kini èyín rí sọ sì aṣọ oge rẹ ...
Read More
Wọn tí dá eérú sójú sójà mokanla - Akoni ni gbogbo wọn

Wọn tí dá eérú sójú sójà mokanla - Akoni ni gbogbo wọn

Tí ẹ bá wà nílè tẹ ẹ ń jẹyan oko, tàbí ẹ wá lóde àríyá níbi ti fàájì tí gbé dùn yungbayungba; ẹ má gbegbe wí pé àwọn kan wà l'Òkè Oya tí...
Read More
Ìbàdàn setan láti gbalejo Omoyele Sowore, oludije fún ipò aare lodun 2019

Ìbàdàn setan láti gbalejo Omoyele Sowore, oludije fún ipò aare lodun 2019

Gbogbo Ìbàdàn tí ń rọ kẹ̀tíkẹ̀ti báyìí láti gbalejo Omoyele Sowore, olootu àgbà àti oludasile ilé ìṣe ìròyìn Sahara Reporters, ẹni tí ń múra...
Read More
"Boko Haram pa ènìyàn méjìlá, wọn tún padà wá pa mẹẹdogun níbi wọn ti ń sìnkú àwọn méjìlá akoko"- BBC Hausa

"Boko Haram pa ènìyàn méjìlá, wọn tún padà wá pa mẹẹdogun níbi wọn ti ń sìnkú àwọn méjìlá akoko"- BBC Hausa

Ileese ìròyìn BBC, ẹ ka tí èdè Hausa tí kéde bí àwọn Boko Haram ṣe pa ènìyàn méjìlá ni Zamfara. Bákan náà ni wọn tún padà wá lọ́jọ́ kejì níb...
Read More
Ọmọbìnrin to gbé ọyàn sì bàbà rẹ lẹ́nu: Ìṣẹ̀lẹ̀ to wáyé láàárín àwọn òyìnbó aláwọ̀ funfun

Ọmọbìnrin to gbé ọyàn sì bàbà rẹ lẹ́nu: Ìṣẹ̀lẹ̀ to wáyé láàárín àwọn òyìnbó aláwọ̀ funfun

Arábìnrin Mercy Makinde lo ṣe àfihàn àwòrán yìí pẹ̀lú akole to wá nisale yìí lórí ayélujára. Ìṣẹ̀lẹ̀ ojú ayé gidi ni, kìí se arosọ rárá. Ì...
Read More