Omoyele Sowore wọlé sí Naija pelu òkìkí nla Olayemi Oniroyin 4/03/2018 08:34:00 pm Add Comment Edit Àìmọye lọ tú jáde lónìí láti kí Omoyele Sowore , Olóòtú ìwé Ìròyìn Sahara Reporters , ẹni tó setan láti díje fún ipò ààrẹ kaabọ sì orileede ... Read More
Happy Birthday! Mama Kunle Afolayan pé ní ọdún márùndínlọ́gọ́rin (75) Olayemi Oniroyin 4/03/2018 07:59:00 am 1 Comment Edit Mama Kunle Afolayan pé ẹni odùn márùndínlọ́gọ́rin láyé. A gbàdúrà ire àlàáfíà, ìdùnnú àti èmi gigùn fún mama. Igba ọdún, ọdún kan ni. Ha... Read More
Gómìnà ipínlẹ̀ Kano fi ori ru iyẹ̀pẹ̀ lónìí Olayemi Oniroyin 4/02/2018 08:33:00 pm Add Comment Edit Ẹnu yà ọ̀pọ̀lọpọ̀ lónìí nígbà tí gómìnà ipínlẹ̀ Kano, Abdullahi Ganduje, ṣe abewo si ise àkànṣe kan tí ń lọ lọ́wọ́. Gómìnà rí àwọn ènìyàn t... Read More
"Emir kìí se èdè Hausa", àlàyé Ọ̀jọ̀gbọ́n Farooq Kperogi tí ṣàlàyé ohun tó rújú Olayemi Oniroyin 4/02/2018 07:56:00 pm Add Comment Edit Ọ̀jọ̀gbọ́n Farooq Kperogi ọmọ Nàìjíríà tí ń sise olùkọ́ni ni ilu America tí ṣàlàyé wí pé, ìkà àbùkù nínà láàárín Yorùbá àti Haúsá láti ìgbà... Read More
Igbo Sambisa: Ohun tí àwọn sójà ń ṣe lojo àjíǹde ni yìí Olayemi Oniroyin 4/02/2018 01:47:00 pm Add Comment Edit Láàárín àwọn ọ̀tá, níbi tí ota ìbọn tí ń fò bí ẹyẹ ojú ọ̀run, nínú igbó aginjù Sambisa, àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà péjọ pọ̀ fún ìsìn àjíǹde. Wọ... Read More