Aṣọ Mercy Aigbe to dá wàhálà silẹ ni yìí Olayemi Oniroyin 5/10/2018 11:08:00 pm Add Comment Edit Àríyá... níbi ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Kemi Afolabi. Àwọn ènìyàn sọ wí pé aṣọ ti Mercy Aigbe wọ kò dára tó nígbà ti àwọn kan rí gẹ́gẹ́ bí oge lásán el... Read More
Gani Fawehinmi àti Fela Anikulapo Kuti Olayemi Oniroyin 5/10/2018 11:07:00 pm Add Comment Edit Read More
Odunlade Adekola yege: Irawo osere náà kàwé gboyè Olayemi Oniroyin 5/10/2018 11:01:00 pm Add Comment Edit Kò sí ìgbà táa dásọ tá rilẹ fiwọ́. Odunlade Adekola tí padà kàwé gboyè. Congratulations 🎊 Read More
ORÚKỌ ÀWỌN ALÁÀFIN Ọ̀YỌ́ TO TÍ JẸ ṢÁÁJÚ KÒ TO WA KAN ALÁÀFIN ÀSÌKÒ YÌÍ Olayemi Oniroyin 5/10/2018 06:42:00 pm Add Comment Edit ORÚKỌ ÀWỌN ALÁÀFIN Ọ̀YỌ́ TO TÍ JẸ ṢÁÁJÚ KÒ TO WA KAN ALÁÀFIN ÀSÌKÒ YÌÍ 1 - Oranmiyan 2 - Ajaka 3 - Shango 4 - Aganju 5 - Kori 6 - Olu... Read More
Lára ohun tó mú Yorùbá yàtò gedegbe ni yìí Olayemi Oniroyin 5/10/2018 06:36:00 pm Add Comment Edit Yorùbá kìí rìn ìrìn ìdọ̀tí. Yorùbá kìí wọ akisa. Yorùbá lónìí ká wọ buba, ká wọ ṣòkòtò, ká wá gbé agbádá le e lórí. Yorùbá lo ní ká rí ẹni,... Read More