"Mo má ń sọ fún àwọn ènìyàn wí pé Kositọma mi àtijọ́ ni gomina ṣùgbọ́n wọn kì í gba mi gbọ - Ìyá Dare onigbin ni Owena. Ó ti pe tí Ìyá...
Read More
Home / All post

Buhari tí de láti UK: Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Orunmila tí ṣẹlẹ̀ sí Buhari
Ààrẹ Muhammadu Buhari tí padà wálé láti ìlú Biritiko níbi tó ti lọ yọjú sì dókítà tí ń tọju rẹ. Ní alẹ ọjọ́ Jimoh, 11/05/18, ní bàálù aare b...
Read More

City People Magazine ṣetán láti dá Adegbodu Twins lọ́lá
Awon Aláṣẹ City People Magazine tí ṣetan láti ṣe ayẹyẹ idalọla fún àwọn ìbejì Adegbodu fún ipa ribiribi tí wón tí kò ti a ba n sọ nípa ojúló...
Read More
Kò sí ìgbà táa dásọ tá rilẹ fiwọ́
Enikan ra motor lónìí , bóyá lẹ́yìn ọdún márùn-ún tàbí mẹ́wàá ni Èdùmàrè to gbọ́ àdúrà rẹ. Ìwọ náà ra, adùn ibẹ ni wí pé, motor àsìkò ni ti ...
Read More

Ìrìn àjò wákàtí kan: Ọkọ̀ ojú irin Ibadan d'Eko ti fẹ́ parí - Kongila
Ìṣe ń lọ lọ́wọ́ báyìí nípa ìṣe ọna ojú-irin tí reluwe yóò má rìn láàárín ìlú Èkó sì ìlú Ìbàdàn. Àwọn agbase ṣe náà so wí pé, oṣù Kejìlá ọdún...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)