Boko Haram gbiyanju lati fẹ̀mí ṣòfò nínú awẹ Ramadan Olayemi Oniroyin 5/21/2018 11:25:00 pm Add Comment Edit Àìmọye èmi ni Boko Haram kò bá rán lọ sọ́run lópin ọsẹ tó kọjá yìí, 20/05/2018, níbi wọn ti n gbìyànjú láti dáná bombu 💣 sì mọsa... Read More
Ọkùnrin ní má fi oyún inú mi bí - @LindaIkeji Olayemi Oniroyin 5/21/2018 10:55:00 am Add Comment Edit "Mi ò lè pa ayọ̀ yìí mora mọ. Ìdùnnú mi lo jẹ láti kéde rẹ fún yín wí pé, àkọ́bí ọmọ mi kò ní pẹ́ de ba mi lálejò ni nǹkan bí oṣù kan s... Read More
Dangote tí bẹ̀rẹ̀ si ni ṣe moto Peugeot jáde báyìí Olayemi Oniroyin 5/21/2018 10:50:00 am Add Comment Edit Alhaji Aliko Dangote, ènìyàn dúdú to lowo ju lagbaye tí ṣetan báyìí láti má ṣe àwọn ọkọ pijó jáde ní ìlú Kaduna. Dangote Peugeot Automobile ... Read More
"Ojú tí Nìyí, Toyin Abraham ti pàdé ọkọ tuntun oloriire" - Àwọn tí Toyin fò fáyọ̀ Olayemi Oniroyin 5/21/2018 10:42:00 am Add Comment Edit "Ojú ti Nìyí aronipin! " Awọn olólùfẹ́ Toyin Abraham ti gbogbo ènìyàn mọ sì Toyin Aimakhu tẹ́lẹ̀ tí ń bá yọ báyìí pẹ̀lú bi òṣerébì... Read More
Àwọn ará ìlú ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí fún ọlọ́pàá "yellow fever" olótìítọ́ Olayemi Oniroyin 5/19/2018 01:44:00 pm Add Comment Edit Àsegbé kan kò sì láyé, àsepamọ́ ló wà. Ọkùnrin tí orúkọ n jẹ Ifedioranma Darlington tí ń sisẹ́ adari ọkọ̀ ojú pópónà ni ìkòríta Aroma nílùú... Read More