Smiley face

'Ife Wa Gbona Gan-an'- Iyawo Yobo

Iyawo Joseph Yobo, Adaeze ti ko leta pada ranse si awon ti won se enu won sakasaka nipa ife oun ati oko re wi pe ife won ko rese duro mo ati wi pe afaimo ki ipinya ma waye.

O ni gbogbo ohun ti won n so pata aheso lasan ni. O ni ife oun ati Yobo si n gbona felifeli.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment