Smiley face

Owo Ti Te Awon Omo Naijeria Ti Won Se Ise Asewo Ni Ilu Spain

Awon omo Naijeria bi meedogbon ti won n ko awon omo obirin lo se ise asewo ni ilu Spain ni owo awon olopa ti te bayii.

Awon wonyii ni won ri pelu iwe irinna ayederu ati opolopo dukia olowo iyebiye.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment