Nigba ti yoo tun fi di ojo Abameta awon aworan ipolongo yii tun legbakajorinlo, a fi bi eni wi pe awon alujannu ni won le awon aworan naa loganjo oru ni.
Bi o tile je wi pe ko si afihan ipo kan pato ti Akala fe dije fun lodun 2015, sugbon ohun to daju ni wi pe Christopher n pada bo sinu ijoba.
Aworan ipolongo Akala nikan ko, Seyi Makinde naa tun ti bere ipolongo tie naa eleyii to se afihan re gege bi oludije fun ipo gomina Ipinle Oyo lodun 2015.
Inu egbe PDP kan naa si ni Makinde ati Akala si wa.
Odun 2015 ko ti i de, sebi Mariwo lasan ni mbe lojude. Mariwo ko si to Eegun. Gelede lopin iran.
0 comments:
Post a Comment