Smiley face

Ijamba Oko Lori Afara Mainland Ni Ilu Eko Mu Emi Lo

Awon Yoruba ni asare tete ko ni koja ile, arin jeeje ko ni sun sona. Awon ti isele naa soju won so wi pe ere asapajude lo sokunfa ijamba oko to waye lonii lori biriji Mainland ni Ipinle Eko.

Ori ere ti oko Prado SUV naa wa lo mu padanu okan ninu awon taya ese re eleyii to da oju gbogbo oro ru bi Onibode Ilu Lalupon.

Eniyan meji ni mbe ninu oko naa nigba ti isele naa sele. Okan ku loju ese nigba ti ekeji wa lesekan aye ese kan orun bayii.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment