Arewa obirin to joye oba oge ilu Venezuela ni odun 2004, Monica Spear ni awon amokunseka kan ti rojo ibon fun laya pelu oko re, Thomas Berry ti won jo n lo ninu moto mesi-oloye ti n gbe won lo ni ilu Venezuela.
Awon olopa ilu naa ti bere iwadii bayii nipa iku ojiji eleyii to mu toko-taya sun sinu agbara eje ti san loju titi masose Valencia si Puerto Cabello.
Nibayii, enikeni ko ti le so pato ohun to sokunfa isele buruku yii. Sugbon gege bi iwadii Olayemi Oniroyin, ilu Venezuela wa lara awon ilu to n lewaju ninu ipaniyan, idigunjale ati ijinigbe lagbaye.
Omo odun mokandinlogbon (29) ni Monica. Arewa naa si ti fi igba kan dije fun Miss Universe naa ri.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment