![]() |
Jack Bauer Okunrin Ogun |
To ba je wi pe eyin ti wo fiimu Jack Baur okunrin ogun ti won pe akole re ni 24hours tele, Mariwo lasan leri egungun sese fe e jade bayii ni. Won ti n ya itesiwaju fiimu naa lowolowo bayii ni ilu London. pupo awon agba osere inu fiimu naa ti e mo naa le o tun maa ba pada.
'Ilu London la wa yii. Gege bi eyin naa se ri wi pe idan lo (Jack Bauer n soro yii nigba ti awon asarologe n da eje pupo si lori gege bi eda-itan to fara pa ninu ijamba moto). Idan inu fiimu eleyii de tun ma 'Kos trouble' ju ti ateyin wa lo'.Kiefer Sutherland ( Jack Bauer)
Oludari ere n se apejuwe bi Jack Bauer yoo se fi ibon pa awon ota re ninu fiimu naa
Awon asaraloge pelu Jack Bauer
Bi Jack Bauer se n ya fiimu re lowo ni ilu London, emi gan-an ya temi lowo ni ilu Naija nibi. O ya, e yewo ke e ri bo se ta lenu yeriyeri. [Oruko Mi Ni Jack Bauer]
Kini akole ere Na
ReplyDelete