Láìpẹ́ yii ni iwe iroyin kan jade eleyii to n salaye wi pe 2Face ti fun omobirin osisẹ banki kan loyun ti orukọ rẹ n jẹ Taniola. O jọ bi ẹni wi pe Innocent Idibia ati iyawo re ko fi oju ire wo ọrọ naa rara, eleyii ti won lo jẹ irọ́ lasanlasan. Tuface lo kọkọ fi aidun rẹ han si iroyin naa, nibayii iyawo rẹ naa ti n fi èpè ranse si awon oniroyin to se apejuwe won gẹgẹ awon eniyan ti ọpọlọ won ti dorikodo.

0 comments:
Post a Comment