Oserebirin Stephanie Seymore to tun un sisẹ afihan oge ko yèé ya orisiirisii awon aworan pelu awon omo re okunrin ti won ti balaga eleyii ti n kọ opolopo awon eniyan lominu. Lara iru awon aworan yii naa ni eyi to ya leti okun lai wo asọ pelu ọkan lara awon omo rẹ, Peteru nibi ti omo re ti n fi ẹnu kò ó lẹnu, ti omo si n fi ọwọ tẹ iya rẹ lọyun.
Ọmọ rẹ salaye wi pe ko si nnkankan laaarin oun ati iya oun, ati wi pe aworan lasan ni eleyii to ni iya rẹ n lo gẹgẹ bi onísẹ́ asafihan oge ati ẹwà ara.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment