Smiley face

Iyawo Tuface N Jaye Ọlọba Ni Yankee


Awon aheso ọrọ ti n fo kiri wi pe Innocent Idibia ti fun omobirin kan loyun ti di ohun ti Annie Idibia kò rí rò rara pẹlu bi o se n se faaji ara rẹ kiri ni ilu Amerika pelu ọmọ ati awon ojulumọ.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment