
Akiyesi awon eniyan nipa aworan tuntun Ini Edo ni wi pe oserebirin naaa
ti jò diẹ si ju bi o ti wa tẹlẹ lọ. Eleyii ti ko si mu adiku ba ẹwà rẹ
rara. Kaka ki ẹwà obiriin naa din, o tun peleke si i ni.

Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
2/18/2014 02:56:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment