Paul Okoye ati ololufe re, Anita Isama ti pada mu ojo igbeyawo tiwantiwan won eleyii ti yoo waye ni ojo kejilelogbon osu keta odun yii ni Aztech Arcum Events Centre to wa ni ilu Port Harcourt.
Edumare, ba so ojo naa di ojo idunnu fun toko-taya. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment