
Owo awon osise Nigeria Security and Civil Defence Corps (NSCDC) ti eka Ipinle Oyo ti te awon onise ibi kan pelu ori eniyan ni owo won ni ojo Abameta to koja yii ni agbegbe Iware to wa ni Ijoba Ibile Afjio ni Ipinle Oyo.
Gege bi a se gbo, eje si n kan sile to-to-to lara ori tutu naa ti won ka mo won lowo eleyii ti n se apeere wi pe won sese se ise ibi naa ni.
Awon ti owo te naa ni Adebayo
Afeez, Amidu Ogunjimi, Sherifat Mufutau, Taibat Lasisi, Waheed Wahab ati Oyeniyi Oyeniran.
0 comments:
Post a Comment