Sebi isonrongbesi, isunmu si ni igbete ga. Awon oniroyin ti to Oserebirin Mercy Aigbe lo leyin ami eye Africa Magic to gba lati bere ero ati asiri aseyori re. Mercy Aigbe ko tile ronu leekeji ko to fun won lesi oro, 'Edumare lo fere si ise mi ogbon ori ko'.
E le ka nipa awon osere ti won gba ami eye Africa Magic 2014 [NIBI]
0 comments:
Post a Comment