Sebi ti oge ba po lapoju bi were ni i so eniyan da. Bi o tile je wi pe lati igba lailai ni awon eniyan ti n ya orisiirisii aworan si ara won gege bi oge sise. Igba olaju tun de ni gbogbo eniyan tun ya tattoo sara. Bi eniyan ba fe wa ya tattoo, nje a le pe iru awon wonyii ni tattoo bi? Ko maa lo je wi pe tattoo orun apaadi ni awon eleyii abi eyin le se iru tattoo bayi sare ni?
Sibesibe, kokojabele. O hun ti o ba wu eniyan lo le se si ara re.
0 comments:
Post a Comment