Smiley face

Awon Onwoye Ere Boolu Agbaye Ti De Stephen Keshi Lade Oye Tuntun


Sebi awon Yoruba lonii ti ori ba pe nile yoo dire. The Institute of Football Coaching and Statistics ti kede olukoni elereboolu alafesegba ti ile Naijeria,Stephen Okechukwu Keshi  gege bi olukoni to wa ni ipo Merinlelogun (24th) ninu awon olukoni ere boolu to daraju ni ti awon egbe agbaboolu orileede lagbaye. Olukoni ti ilu Spain, Vicente Del Bosque lo wa ni ipo kinni, Ti ilu Jamani, Joachim Low lo wa ni ipo keji, nigba ti Oscar Tabarez ti ilu Uruguay wa ni ipo keta lagbaye. Lori ate igbelewon naa, olukoni ile Naijeria lo je eni to wa loke patapata laaarin awon orileede ile adulawo yoku.

Eyin tun le wo awon toku [NIBI]

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment