Awọn eniyan bi mejidinlọgbọn (28) lo koja lọ sọrun nigba ti awon eniyan to le ni ọgọrun fara pa lonii ni ilu China nigba ti awon eniyan alasọ dudu kan sadeede yawọ ibudoko ọkọ̀ ojurin Kunming Railway Station to wa ni Yunnan ti won si bẹrẹ si ni pa awon eniyan ni ipakupa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment