Aimọye awon ololufẹ ere bọọlu ni won se agbako iku lonii, ọjọ kinni osu kẹta ọdun ni agbegbe Ajilari to wa ni Maiduguri ni Ipinle Borno pẹlu bi ado oloro se dun lojiji ti gbogo awon eniyan ti won wa nibi iworan naa si segbe loju ẹsẹ.
Iwadii se alaye wi pe awon ọmọ ikọ Boko Haram ni won ti wa ri àdó olóró yika gbegbe naa saaju akoko iworan ere bọọlu eleyii ti ẹnikẹni ko si fura rara.
0 comments:
Post a Comment