Lojo Aje to koja yii ni awon omo Naijeria to wa ni ilu Jamani se iwode lati fi ehonu won han nipa bi awon ijoba ilu Naijeria se n se owo ilu naa mokunmokun ati eto abo Naijeria ti ko dara rara. Opopona Neue Jakobstrasse ni iwode naa ti waye nibi ti ile asoju ile Naijeria wa.
0 comments:
Post a Comment