
Ise amuludun ti lu jara won, olorin n sere itage, onise sinima n korin faye jo. Awon Yoruba si ti pari oro, won ni ka roso modi ka rodi ma so, sebi kidi ma ti gbofo ni. 2face Idibia ti n mura lati foju han ninu sinima kan ti won pe akole re ni 'Make a Move'. 2face nikan ko, Omawumi ati Denrele Edun naa ko gbeyin ninu ise opolo naa. Inu osu kefa odun ni a nireti wi pe fiimu naa yoo jade lati owo Ivie Okujaye
.
0 comments:
Post a Comment