
Ilu Mali ti setan lati se afihan awon ohun eroja isembaye ilu naa fun awon arin irin-ajo-afe to n lo si ilu naa. Pupo ninu awon ohun isembaye naa lo je awon ise ona bi ere ati awon aworan to n se afihan igbe aye awon eniyan nigba lailai. Yato si awon ise ona orisiirisii, ilu Mali tun se tan lati mu awon arin irin-ajo-afe de awon ibi kan eleyii ti n se apere itan ilu naa gege bi orisun ati igba iwase ilu Mali.
0 comments:
Post a Comment