Smiley face

Se Otito Ni Wi Pe Abass Akande Fadiya?

Omobirin to pe oruko ara re ni Olanike Olaiya lo gba ago awon olopa lo lati lo fi ejo Alhaji Abass Akande sun awon olopa gege bi eni to fi ipa ba a ni ajosepo. O tun se alaye wi pe okunrin olorin Fuji naa ti o se ileri lati ran oun lowo ninu okowo ti oun n se tun fi oruka si oun ni oju ara leyin ibalopo tipatipa lojo ti oun lo sun si ile re eleyii to  fa bi eje se n da ni ara re.
 
Awon olopa ti gbe Abass Akande, oro enu PK1 si ni wi pe ololufe oun ni omobirin naa ati wi pe lotito lo so fun oun wi pe eje n da ni ara re leyin ibalopo oun si so fun wi pe ko lo si osibitu. Omorapala tenu mo wi pe oun ko fi tipatipa ba omobirin naa ni ajosepo, o si ya oun lenu bi okiki iroyin naa se kan wi pe Oba Asakasa fadiya.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment