
Leyin ijamba oko to sele si omo Oba Jide Kosoko, ara agba osere naa ti n pada bo si po. Lojo Eti to koja yii ni Jide Kosoko ni ijamba oko pelu moto Ford Sport Utility re eleyii to run jegejege bi aso inu apere. Jide Kosoko to se ojo ibi re ninu osu kinni odun yii se alaye ewu to fo o da gege bi aanu lati odo Olorun oba.
" Mo fi ope fun Olorun bi o se da emi mi si. Isele buruku naa sele ni Ikeja Shopping Mall ni bi ere Bola Tinubu. Ijamba naa waye latari bireki oko mi to ja eleyii to mu oko naa maa ya sotun ati si apa osi lai dawo duro. Sugbon ni ona iyanu, Edua oke da emi mi si'
0 comments:
Post a Comment