
Oro lori owon gogo epo bentiro ti opolopo awon eniyan sebi ko ni pe di irorun tun bo n buru si ni pelu bi won se n ta jala epo kan laaarin igba naira (200) si oodunrun naira(300) lojo Aje di ojo Isegun to koja yii yato si naira metadinlogorun (97) ti ijoba ni ki won maa ta awon epo naa. Aimoye ile epo ni ipinle Eko ati Cross River lo si kun fun opolopo awon onimoto ti won tiraka ati ri epo ra soko ati awon ipinle mii kaakiri ile yii.
0 comments:
Post a Comment