Orisiirisii ni mbe lori ero ayelukara, orisiirisii eniyan ni mbe laye. Bi o ba je tuntun awon eniyan won a ni awon ko ri iru eleyii ri. Ti Yoruba ba fe fesi ni won n wi pe 'a ko ri iru eleyii ri eru la fi n da ba oloro'. Omokunrin kan to pe ara re ni Tosin Samuel Ayodele Jr lo n be Kemi Omololu Olunloyo wi ko gba fun oun lati ba ni ajosepo ere ife. E ku mo Kemi, won ko ni won ko kun fun un oun naa ko si ni gba laabo. Omobirin onise iroyin naa ti tu asiri omokunrin to se apejuwe re gege bi asewo-okunrin fun gbogbo aye.
E le ka iroyin naa siwaju lori ate Kemi
E le ka iroyin naa siwaju lori ate Kemi
0 comments:
Post a Comment