O ti pe ti mo ti fe bere lowo yin, e joo; se abuku wa ninu ki eyin lomi lara ni?
Tiwa Savage ti bere opolopo ere idaraya lati din ara sisan re ku. Ni ede kukuru, omobirin naa fi di 'Ilepa Sandy'. O ga oo!
Aworan tuntun omobirin naa ni yii pelu akole to gbele e to lo bayii wi pe:
"I was just about to have a burger then I remembered how hard my work out was this morning. Steamed vegetables with fish instead #fitness #weightloss #feelinggood #skinny"
Home / Uncategories / 'O ku Die Mi O Ba Je Burger Laaro Oni Ki N To Daa Pada Bi Owo Baba Ijebu' Tiwa Savage
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment