Paul Okoye ti wo ilu Port Harcourt fun ayeye igbeyawo re to fe waye lola ode yii (Saturday 22nd March 2014) pelu ololufe re, Anita Isama. Opolopo awon irawo lagbo amuludun ni won ti n sokale si Ipinle Rivers fun ayeye alarinrin naa.
Kcee ati Julius Agwu alawada ni won tele oko yawo bale silu Pota.
Ile ise HIP TV ti ori agbagbe DSTV ti se ileri lati gbe ayeye naa bo ba se n sele lowo.
Igbeyawo dun, sebi ase Oluwa ni.
Home / Uncategories / Paul Okoye Ti Wo Ilu Pota Lonii Fun Imurasile Igbeyawo To Fe Waye Lola Ojo Satide
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment