Smiley face

Ina Ti Jo Ile Agbara Hafiz Oyetoro

Ijamba ina buruku kan lagbo wi pe o ti jo ofiisi Hafiz Oyetoro ti gbogbo eniyan mo si Saka ni ajokanle raurau.

Ni Ojobo to koja yii (20th of March) ni ina taa wi yii jo ni eka ti won ti n ko nipa Tiata to wa ni Adeniran Ogunsanya College of Education nibi ti osere naa ti n se ise gege bi olukoni.

E gbo ohun ti Saka so nipa isele naa:

"What can I say, other than to thank God for the gift of life, because no live was lost in the inferno… We actually have good fire extinguishers, but nobody was around to do anything given the time the incident occurred.
Fire fighters have been here but they did little and the authorities have been here too."

"I also lost my promotion letter, most painful was the fact that I was to submit some important documents for some international engagements
but now this may not happen as the documents have also been lost to the inferno," .

E maa gbagbe wi pe laipe yii naa ni osere yii padanu baba re. Adura wa ni wi pe ki Edua Oke ba wa dun Saka ninu. Amin.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment