Smiley face

'Ode Ariya Ni Mo Wa Lojo Ti Chichi Bi Omo Tuntun Fun Mi'- Sound Sultan

Oga ni kaun lawujo okuta, taani yoo so wi pe oun ko mo Olanrewaju omo Fasasi ti gbogbo eniyan n pe ni Sound
Sultan.

Omokunrin olorin yii se ikomo omo re to so ni Abidemi Fasasi (Gbogbo omo olorin ni i je Abidemi, gbogbo igba ni won ki i si nile lojo aya won ba bimo)

Aimoye awon olorin egbe re ni won pejo lati fi ope fun Olorun fun omobirin lantilantin ti Oosa Oke fi ta idile Fasasi lore. 2face Idibia gbori wole, Dayo D1 Adeneye o gbeyin, Timaya lo koko de pelu awon olorin mii ti won jo fi asiko naa se afaaji to letike.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment