Aare Goodluck Jonathan ti lo se abewo si ibi ti isele buruku ado oloro to dun ni Nyanya ni ilu Abuja laaro oni. Bakan naa lo si lo wo awon to farapa ti won wa ni ile iwosan. Aare yo omi loju, awon oro enu re lo si n gbon nigba to n fi aidunnu re han nipa isele naa.
E tun le ka nipa iroyin naa [NIBI]
0 comments:
Post a Comment