Smiley face

"E Yee Lo Ogun Chloroquine Ati Artesunate Mo, O Lewu ooo" -Abajade Tuntun Awon Onimo Isegun

Awon onimo ijinle ti se kilokilo fun gbogbo awon omo Naijeria lati yago fun awon orisii ogun oyinbo kan ti nje Chloroquine ati Artesunate lati wo aisan iba. Won ni ogun na ko dara rara fun omo eranko anbosibosi omo eniyan.

Arabirin Nnenna Ezeigwe to je olori National Malaria Control Programme lo ke gbajari iroyin yii seti gbogbo araye ni ilu Abuja lana.


"If your test result is positive, take only Artemisinin Combination Therapy (ACTs). Do not treat malaria with chloroquine, artesunate or other monotherapies." Oro enu Arabirin Nnenna Ezeigwe
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment