Smiley face

Won Ti Fi Irawo Kun Irawo Kunle Afolayan Pelu Ami Eye Tuntun

Kunle Afolayan ti fi emi imoore han nipa ami eye tuntun ti won gbe le lowo latari ipa ribiribi to ko ninu ise ona to gbamuse ati igbega asa Yoruba to yanranti.

Ohun ti Kunle so ni yii:

"I was honoured with this award of excellence last night for my contribution to the Art and Yoruba culture.

E Seun eyin Illustrious Media Concept. I appreciate."

Olayemi Oniroyin, mo fi asiko yii ki akoni ku oriire, Kongiratulasan!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment